1 |
ení |
2 |
èjì |
3 |
ẹ̀ta |
4 |
ẹ̀rin |
5 |
àrún |
6 |
ẹ̀fà |
7 |
èje |
8 |
ẹ̀jọ |
9 |
ẹ̀sán |
10 |
ẹ̀wá, ìdì kan |
11 |
ọ̀kànlá, ìdìkan lé kan |
12 |
èjilá, ìdìkan l՚ éji |
13 |
ẹ̀talá, ìdìkan l՚ ẹ̀ta |
14 |
ẹ̀rinlá, ìdìkan l՚ ẹ́rin |
15 |
àrúndínlógún, ìdìkan l՚ árǔn |
16 |
ẹ̀rindínlógún, ìdìkan l՚ ẹ̀fà |
17 |
ẹ̀tadínlógún, ìdìkan l՚ èje |
18 |
èjìdínlógún, ìdìkan l՚ ẹ́jọ |
19 |
ọ̀kàndínlógún, ìdìkan l՚ ẹ́sǎn |
20 |
ogún, ìdì méjì |
21 |
oókàn lé lógún |
30 |
ọgbọ̀n, ìdì mẹ́ta |
40 |
ogójì, ìdì mẹ́rin |
50 |
àádọ́ta, ìdì márǔn |
60 |
ọgọ́ta, ìdì mẹ́fạ̀ |
70 |
àádọ́rin, ìdì méje |
80 |
ọgọ́rin, ìdì mẹ́jọ |
90 |
àádọ́rún, ìdì mẹ́sǎn |
100 |
ọgọ́rǔn, àpò kan |
1000 |
ẹgbẹ̀rún, ọ̀kẹ́ kan |